Awon ebi ko gba ki Victor Olaiya gba ipe ori foonu leyin iku Moji omo re

Moji Olaiya, oserebirin onitiata ti o jade laye lonii,18-05-2017, ni orileede Canada leni odun mejilelogoji ti mu ibanuje okan ba awon ololu...
Read More

"Afaimo ki tomato ma gbowo lori pelu kokoro Tuta Absoluta to wole de"- Awon onwoye lo so bee

Kokoro ajenirun kan ti n je Tuta Absoluta ti yawo awon ijoba ibile bi meta ni Ipinle Gombe ti won si ti je gbogbo oko tomato won tan pata. A...
Read More

Ayeye aadota odun (50) ti won da ipinle Eko sile yoo waye ni Jamani:Ayantunde Oyinbo setan lati filu dara

Ayantunde Oyinbo.    Awon egbe agbasaga ile Yoruba ti won kale siluu Jamani, Yoruba Elite Club, ti setan lati se ayeye aadota odun (50...
Read More