Smiley face

Awon Omo Ologun Ile Naijeria Ti Fi Emi Omo Boko Haram Bi Ogota Se Etutu Odun Tuntun

Ibuba awon omo Boko Haram to wa ni
Agbegbe Alafa General to wa ni Ijoba Ibile Baba ni Ipinle Borno gba alejo iku, nigba ti awon omo ologun ile Naijeria pelu atileyin awon omo ologun ofurufu yalu won ti won si pa awon omo Boko Haram bi metadinlogota ni ipakupa lai fi akoko sofo rara.

Eni ti o n soju gege bi igbakeji awon omo ologun to tun je alukoro, Capt. Aliyu Ibrahim Danja je ko ye wa wi pe bi o tile je wi pe Ogun(god of iron) ni omi nile sibesible eje awon omo Boko Haram lo pada fi we.

Gege bi atejade eleyii to buwolu, oni itaporogan naa bere lojo Abameta to koja yii nibi to je wi pe Soja meji pere lo farapa nibi isele naa.

>>>>>
Emi ko ba mu wa gege bi amoran. Ti awon omo ologun ba ti pa awon omo Boko Haran ko ba dara ki won maa fi oku won han wa lori telifisan.

Awon nnkan bayii a maa fun wa ni ireti ati igbagbo ninu ojo ola Naijeria.

Bi Boko Haram ba pa omo Naijeria alailese lorun, iseju kan leyin igba naa yoo ti dori telifisan. Emi ro wi pe sise afihan oku won yoo je bi iwosan si oju ogbe awon idile ti Boko Haran ti pa lekun seyin.

Nje eyin naa gbe pelu mi bi?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

4 comments:

  1. Olayemi walahi o ri so. Otito oro loso. O maa dara ki won maa se afihan re lori Tv. E se

    ReplyDelete
  2. Man u are so right. I agree with u. But I think maybe they decided not to be showing for security reasons or a kind of conspiracy going on somewhere. God Bless Naija

    ReplyDelete
  3. Ok. So, what do think will happen for broadcasting such thing?

    ReplyDelete
  4. Adupe. Pe won tile ri won pa. Ope ni fun Olorun. Emi naa fara mo wi pe ki won maa fi oku won han wa. Eleyii maa mu inu awon ara ilu dun gidgidi gan

    ReplyDelete