Ka ma paro, ile ise Google gbiyanju, mo si ju idi mi soke fun won leemeta.
Boya eyin o ti gbo, ile ise Google ti se afikun ede won pelu ede Yoruba, Hausa ati Igbo labe Ayan Ogufo Google ti a mo si Google Translate.
Eyi ni wi pe eniyan le ko ede Yoruba ki Google Translate yii si Geesii tabi edekede to ba wu yin lagbaye. Bakan naa ni eniyan le ko edekede kale ki eniyan si be Google Translaye lowe lati yi pada si ede Yooba tiwantiwa.
Olayemi, inu mi dun gan-an. Eyi fihan wi pe ede Yoruba ti kuro lede abele bi ti atijo.
E maa je o pe, eyin naa e sare jasi ke e gbose e wo : translate.google.com
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment