Smiley face

Hip TV Gbe K1 de Ultimate Soke Pelu Ami Eye Headies 2013

Emi eye Headies it odun 2013 eleyii ti Hip TV se agbekale re se aponle Oba Fuji pelu ami eye Hall of Fame ti won fi da omo Anifowose lola.

Ifi ami eye danimola yii waye lojo kerindinlogbon osu kejila odun yii nibi ti Olamide ti gba ami eye to poju lo fun ipa ribiribi to ko fun odun 2013 ti a ba n so nipa orin takasufe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment