Sebi e gbo nipa leta ti won ni Iyabo Obasanjo ko si baba re, nibi to ti se apejuwe Aremu Olusegun Obasanjo gege bi opuro, alanikanjopon, baba ti ko bikita fun awon omo re, asaaju buruku ati oloju kokoro eniyan?
E ko le biliifu wi pe iro ni leta naa.
Iyabo fun ra re ti soro lori redio wi pe oun ko ni oun ko leta naa. O ni won kan lo oruko oun lasan ni.
Ta wa lo ko leta naa?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment