Alufa Tunde Bakere ti salaye lojo isinmi to koja yii ni ile ijosin re wi pe opolopo ohun ti Obasanjo ko sinu leta ranse si Goodluck lo ba ohun naa wi nigba to wa loye.
Lara oro re tun ni bi Aare Goodluck se fi eran odun ranse si i eleyii to ni oun da pada. Gege bi oro eni to ti fi igba kan dije gege bi igbakeji aare se so, oni eran odun ko ni awon n fe bikose oju ona to ja gaaraga, ina monamona to peye, omi ero ati igbayegbadun awon ara ilu.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment