Smiley face

Iya Onisu Ti Paayan Ni Ilu Abuja Nitori Betalaifu Meji Pere

Osan oni yii ni isele yii sele.

Iya onisu kan lo n jiyan ogorun naira pelu okunrin kan ni oju oja to wa loju ona Herbert Macaulay ni ilu Abuja.

Katowi-katofo, iya onisu ti gun okunrin ti n ba jiyan lobe pa. Omokunrin naa ti ku bayii, oku re ni won n gbe lo ninu aworan oke yii.

Iya Onisu ti da gobe sile!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment