Smiley face

Justin Bieber Se Ileri Lati Ti Ilekun Ile Orin Re Titi Jesu Yoo Fi De

Awon Yoruba ni bi onirefin ba ni oun ko fingba mo, eleyii to ti fin sile ko le parun lailai.

Agbaoje odomode olorin ile Amerika, Justin Bieber ti kede lori redio to wa ni ilu Los Angeles, California wi pe oun fe fi ise orin sile (o si tun fi kun wi pe o le je titi lailai).

Awon kan ni awada ni, wi pe boya o kan fe sinmi lasan ni.

Sugbon ikede naa ba opolopo awon ololufe re lokan je. Igba ti elomii gbo, n se lo bu sekun peregede lai dake ekun sisun.

Justin Bieber, Omo odun mokandinlogun(19) ti n jaye oloba bi Alaafin tilu Oyo, latun gbo wi pe awo orin tuntun re kan yoo jade lose to n bo eleyii to pe ni "Journal'. Leyin eleyii lo se ileri lati tilekun ile orin re ti ayeraye. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment