Smiley face

Mercy Johnson Se Odun Fun Awon Opo Bi Egberun Marun-un

Sebi won ni enikeni ti iwo ba nipa lati se iranlowo fun oun naa ni enikeji re tooju re.

Oserebirin Mercy Johnson ti fi apo iresi kookan fun awon opo bi egberun marun-un pelu aso opa mefa-mefa fun enikookan won pelu. Lara ebun to tun fi tore ni ororo, iyo, magi, tomato inu agolo abbl.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment