Smiley face

Se Kii Se Wi Pe D'banj Ti Lo N Pade Genevieve Ni Koro?

Olayemi Olofofo mo tun ti de o. Bi mi o ba kuku ri mi o ni so. E tun sun mo bi ke e tun wa gbo tuntun.

Ko maa lo je wi pe Koko Master D'banj ti n pada fe ololufe re igba kan ri pada, Genevieve Nnaji.

Sebi e mo wi pe awon mejeeji ti fe ara awon ri tele ki won to pinya. Abi eyin fe so wi pe e ko mo ni?

Lopin ose to koja yii ni awon eniyan tun ri awon mejeeji papo ni Oceanview to wa ni Victoria Island ni ilu Eko ti won n se ara won rodorodo bi omo tuntun.

Iroyin mii to tun farape ni iforowero kan ti won se fun Igwe ninu osu kewaa odun yii nibi to ti so wi pe Genevieve si wu oun fe gege bi aya.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment