Bi eniyan ba je ololufe orin takasufe, ID Cabasa ko le je ajoji siru eni bee rara.
Olumide ti gbogbo eniyan mo si ID Cabasa ni alagbede orin to se opolopo orin 9ice to di gbajugbaja gege bi Olootu orin kiko.
Bi o se je wi pe ile orin ni ID Cabasa n sun tosan-toru nibi to ti n yi gbogbo e po ko le jo ara won, nibayii won ti fi ifiamiororo yan omokunrin naa gege bi alufa ni ile ijosin Global Impact to wa ni Babs Animashaun ni Surulere.
Paito Olumide, Oluwa yoo ma so agbara yin dotun. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment