Ijamba ina waye laaro oni ni eka Banki Zenith to wa ni agbegbe Dugbe ni ilu Ibadan. Aimoye dukia ni ina naa baje ko to di wi pe awon osise panapana wa dasi isele naa.
Iwadii si n lo lowo nipa ohun to fa isele buruku naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment