Enikeni ti oba Oluwa ba ti fun wa ni ipa ati agbara lati ran lowo - ki ba a se eniyan tabi eranko, eni naa ni enikeji wa.
E ri oore sise gege bi anfaani nla lati se ife okan Olorun to da wa saye. E se oore pelu emi kan lai wo ti eya, esin tabi ipo rara.
Ohun to daju ni wi pe ohun ti enikeni ba se naa ni yoo rigba gege bi esan lati odo Olorun Oga Ogo.
Ti omo eniyan ba le ko sinu omi nitori omo eranko lasan, kilode ti omo eniyan diju oore si omo lakaji ti Edua oke fun ni agbara lati ran lowo?
Gege bi oro Gbenga Adeboye: ' Maa soore bi ipa re ti mo nitori wi pe o rise ju awon kan lo, oo kan mo ni'.
Olayemi Oniroyin, oore ni i maa se emi o ni seka lailai.
IWO NKO?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment