Awon kan so wi pe o seese ko je wi pe awako naa ti mu 'Olomo' yo ni. Awon kan ni Jagunlabi sun lori irin ni. Akiyesi awon mii si so wi pe bireki oko naa lo ja ti oko naa fi yi danu sile.
Oko epo to yi danu lati ori afara Maryland naa fa opolopo sunkere-gbakere oko ni gbogbo agbe naa fun aimoye wakati.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment