Smiley face

Won Ti Le Don Jazzy Papo Mo Rihanna Gege Bi Toko-Taya

Ti ko ba je wi pe won so fun eniyan wi pe ise owo ero komputer ni aworan yii, ni o nira pupo lati gba wi pe agbelero aworan ni. Aworan naa duro rekete bi ere kingsway

Don Jazzy pada soko Rihanna, ko si ohun ti ko le sele ti eniyan ba ni suuru.

#Surulere
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment