Smiley face

Won Ti Pada Tu Asari Dokubo Sile

Leyin bi wakati mefa ti awon osise alabo inu ti ijoba ti a mo si SSS ti gbe Dokubo, won ti pada tu sile ko maa lo ni ayo ati alaafia.

Won ni bi a se pa ogberi a ko gbodo se bee pa omo awo. Bi o tile je wi pe gbolohun yii ko jade ni enu won sugbon ise ati iwa won se apeere ero okan won.

Sebi eni ti ko gbon ni awe n gbo, eni to ba gbon won a gunyan rugudu won a gbe sabe aso. Awon agba ni eegun ti n jo lori omi ni, onilu re mbe nisale odo.


Naija Ilu Ogbon
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment