Aare Goodluck pada wo ilu Ibadan lonii pelu awon igbimo elenu merindinlogun lati wa yo ayo ayeye ojo ibi ogorun odun (100) ti Olubadan ti ile Ibadan, Oba Samuel Odugade se lana eleyii ti ko raye wa latari ijamba to sele.
Ilu Kano ni Aare gba wole nibi to ti lo gba gomina ilu Kano tele wole pada sinu egbe PDP ki baalu re to ba si papako ofurufu Alakia to wa ni Ilu Ibadan.
O dabi eni wi pe awon eniyan to ku lana ni ti won ti tan, Aare Goodluck ti pada sori eto re lai si girigiri.
Leyin ijamba to waye lana, awon omobirin bi ogun tun ti bo sowo Boko Haram lonii ni Ipinle Borno.
Olayemi Oniroyin, ohun to ye mi ni wi pe ika eniyan ko le je lo titi aye. To ba je lonii, to je lo lola ko le je titi aye rayeraye. Sugbon gege bi oro awon omo Odu-to-da-iwa, ki ile to pa osika eda nko?
Home / Uncategories / Aare Jonathan Ti Pada Wo Ilu Ibadan Lati Wa Ki Olubadan Fun Ayeye Ojo Ibi Re Leyin Ijamba Ado Oloro To Dun Ni Ilu Abuja
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment