Smiley face

Asiri obirin To Toju Cocaine Si Oju Ara Tu Si Owo Awon Agbofinro

Owo awon ajo NDLEA ti te arabirin kan ti oruko re n je Chinelo Lynnette eni odun merindinlogoji (36) to gbe ogun oloro cocaine pamo si oju ara re ni papako ofurufu Murtala Muhammed to wa ni ilu Eko.
 
Gege bi oro olori ajo NDLEA, Ogbeni Hamza Umar ti eka ti papako ofurufu se salaye isele naa fun awon oniroyin, o ni oju ara ni omobirin naa ki ogun oloro naa si ki asiri re to tu bi akara to tu sepo.
 
"The suspect tested positive for drug ingestion and vagina insertion. She expelled a total of 685g of substance that tested positive for cocaine while under observation at the airport."
 
 
Gege bi oro awon Yoruba, won ni ti won ba beere idi ti eye gunnugun fi pa lori dandan ni ko ri wi, ti won ba si beere idi oro nipa gege ti mbe lorun akalamagbo dandan ni ko ri oro so fun gbogbo eniyan. Chinelo Lynnette naa so ti e jade wi pe n se ni won ti oun si iru ise buruku bayii ati wi pe kii se nipa ife okan oun ni rara.
 
"I am a food vendor at Ajangbadi, Lagos, and have never been involved in crime. I was abandoned by my husband two years ago and left to cater for our children alone. All this while, I have been doing my best to provide for them and pay their school fees.
 
"The last straw that broke the camel's back was when the landlord ejected me; I had nowhere to turn to for solace. While I was crying, a man who I did not know came to console me. He promised to help by introducing me to the importation business. I felt he was God sent until he sponsored my trip to Addis Ababa. It wasn't until I got to Ethiopia, that I knew it was drug trafficking. When I tried to refuse, he threatened to recover his investment at all cost." 
 
 
Oga agba awon ajo NDLEA, Ogbeni Ahmadu Giade naa fi kun wi pe o jo bi eni wi pe awon onise ibi ti won n gbe ogun oloro ti lo tun Ifa da ati wi pe won ti paaro awon ona ti won n gbe ogun oloro gba yato si ohun ti awon mo won mo tele.
 
E gbo ohun ti oga agba naa so:
 
"Going to Addis Ababa to smuggle cocaine into Nigeria is one of the tricks employed by drug trafficking syndicates. Cocaine is not known to come from Addis Ababa, but we were able to detect it because of our vigilance. Members of the public should at all times be conscious of the tricks employed by drug syndicates. We look forward to fruitful progress in our investigation at the end of which the suspect will be charged to court."

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment