Atejade Yinka Ayefele Nipa Ile Re To Jona Laaro Oni
Olayinka Ayefele ti se atejade fun awon oniroyin nipa isele ijamba ina to sele ni ile re to wa ni ilu Ibadan lonii (15/04014).
Ayefele ko fi mo ni eleyii nikan, MON tun bo si ori Facebook lati dupe fun emi ife ti awon eniyan fi han si.
Ohun ti Oba Tungba Gospel so ni yii:
"Thank you all for your love and concerns. Everything is under control. Gbogbo wa koni rija ina o."
Olayemi, mo sami mo gbe ito amin mi.
0 comments:
Post a Comment