Awon onise ibi kan ti won fura si gege bi Boko Haram ti lo ju ado oloro si ago olopa kan, banki ifowopamo ati kootu Sharia to wa ni Ipinle Jigawa.
Awon olopa bi meje ati awon eniyan mii ti won wa ni agbegbe Gwaram Sabuwa to wa ni ijoba ibile Gwaram lo ba isele buruku yii lo.
Isele buruku yii waye ni nnkan bi ago kan oru si meji ni Ojoru to koja yii(9/04/14).
Home / Uncategories / Awon Boko Haram Ti Fi Ado Oloro Fo Ago Olopa, Banki Ati Kootu Sharia Ni Ipinle Jigawa
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment