Mo ri ohun ara oto to le ku lonii. Sugbon e maa bere lowo mi nipa ohun ti mori. Omidan Dunnie re e, omo Naija ni sugbon Amerika lo fi sele, ise Ariya ati ise oge aso nise ti n se. Awon aworan to ko sori agbagbe Intsagram re ree. E maa je n tan yin, gobe ti sele nibi o. Ohun to fa gobe gan-an lori agbegbe ko ti ye mi. E joo, e ri daju wi pe iyawo yin ko si nipako yin nigba ti e ba n wo awon aworan yii , ki gobe maa tun lo sele nile yin. E tesiwaju lati wo awon aworan to ku. Mo ri yin na.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)









0 comments:
Post a Comment