Awon Yoruba ni pepeye kii ku iku omi nibi to ti n ba omi sere, oro yii ni Mercy Aigbe gbo lo ba ko gbogbo ebi re lo seti okun lo we. Iyekan alabahun ko ju meta lo, Mercy Aigbe Gentry ni akoko, oko re Lanre Gentry ni eleekeji, nigba ti Omogbolahan omo won si je eleeketa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)




0 comments:
Post a Comment