Smiley face

Ijakadi Laaarin Wizkid Ati Awon Ololufe Re Lori Twitter

Dirama sele lori ero Twitter Ayo Balogun lojo Aje to koja yii nigba ti oun ati okan lara awon ololufe re jo gbe peregi kana.
 
Olufe Wizkid lo koko tahun si omo naa to wi pe foto lasan ni Wizkid n ya kiri ori ero iwiregbe re.
 
'All Wizkid has done this year is take instagram pictures'.
 
Wizkid naa ko je ko tutu rara nigba to fun lese oro re pada ni gbigbona:
 
"He's probably made more money than the fan has ever made in life!'
 
Bi won se bere re ti gbogbo re fi foju po.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment