Smiley face

Ile Tuntun Wo Ni Ilu Eko

Ile tuntun kan ti won n ko lowo dawo lule lOjobo to koja yii ni opopona Alonge to wa ni agbegbe Oworonshoki ni ilu Eko. Awon eniyan bi mewaa ni ile yii bo mole eleyii ti ori pada ko gbogbo won yo pelu bi won se selese ni gbogbo ara. Lara awon eni fara selese naa ni Moses Atoketi 15; Jimoh Adebiyi 13; ati Monday Ahungbe 12; ati awon eniyan meje mii ti won je osise ile naa.
 
Okan ninu awon ti isele naa soju re salaye ohun ti oju won ri fun awon oniroyin
 
"The building collapsed around 11.30am. Ten people were working at the building when it collapsed. The house used to be an unoccupied bungalow, but about seven months ago, labourers started working on it.
 
"The building was being upgraded and was to be converted to a two-story building.
 
"Luckily for the victims, the building is located near the Oworonshoki Police Station, so we were able to rally around and we called emergency officials who immediately rushed down to the scene."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment