Smiley face

Kini Kola Olootu Fe Se To pe Osupa Ati Oga Nla Papo Lojo Kan Soso?


Gomina egbe sorosoro Ipinle Oyo, Otunba Akolawole Olootu ti setan lati seye ikeyin fun awon obi re mejeeji ti won se atona re wa sile aye. Adura awon obi ni wi pe ki omo won gbeyin won, adura omo naa ni ko gbeyin arugbo re. Adura Olootu gba, omo rere si ti setan lati se eye nla fun awon obi re. Atejade Akolawole Olootu re e.

This is to inform you that my Dad and Mum's Funeral Ceremony is coming up on 8th of June (Sunday) 2014 at Mauve Event Center, Ring Road, Ibadan, Oyo State, Nigeria. Time 10am to 6pm. Music by Yinka Ayefele, Wasiu Alabi Pasuma Oga Nla1, Ramon Akanni and Shaeed Osupa Oba Nla 1. The hosts are Alhaji Rasheed Ayinde and Taye currency. For further enquiries on invitation and Aso Ebi pls call 08033319700 or BBM 7D7652EA Ire ooo .

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment