Smiley face

Kini Mourinho Se Nigba To Ku Iseju Meta Ki PSG Sunkun Pada Sile?

Jose Mourinho to je olukoni fun egbe agba boolu Chelsea ti salaye wi pe oun ko lo sajoyo pelu awon omo oun nikete ti goolu eleekeji to pa PSG lekun wole sinu awon (net). Mourinho se alaye wi pe oun lo ko won nijanu ni, nitori wi pe ijafara lewu gan-an.
 
 
'Not celebrating. To tell Fernando and Demba the changes we had to do because three minutes plus extra time the way we were playing was too risky.'
 
 
Ninu Iroyin mii to jade, agbo wi pe Mourinho da awon jagunjagun owo iwaju re meji pada seyin lati lo di ile mu tori ki omi ma ba a teyin wo igbin lenu ni iwonba iseju perete to ku ki ifese wonse naa pari.
 
Egbe Chelsea pada bori ifesewonse naa to waye lojo Isegun to koja yii pelu ayo meji si oodo (2-0) ti gbogbo ayo ti won ta nile-loko si ku si eeta si eeta (3-3) eleyii to mu egbe Chelsea kesejari lati kopa ninu igbese to kangun si asekagba ti idije Chamopion League ti n lowo.
 
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment