
Lola aya Peter Okoye (P-square) lo n fi oro naa sawada pelu bo se se afihan aworan tuntun awon omo re lo agbagbe Instagram.
Lola yii kan naa lagbo wi pe o sokunfa ija to be sile laaarin awon omo ibeji olorin (P-square) to waye ni kopekope yii. Sugbon nigba ti ija pari tan, awon omo Okoye ni iro ni iroyin to wi pe Lola ni eja nla ti n danu ibu ru gbudugbudu. Won mistake po ninu iroyin taa gbo tele.

0 comments:
Post a Comment