Smiley face

Omo Genevieve Ti Di Agbalagba Omoge

Edumare ma pa omo fun olomo. Bi Genevieve Nneji ko tile si ni ile oko kankan bayii, Oba oke ti fi ayo si inu aye re pelu orekelewa omobirin ti Oba Adaniwaye fi ta lore. Chimebuka Nneji ni oruko omo naa n je. Ti eyin ba si ni 'intireesi' ninu omo naa, e je tete bere si ni i dana re ki won to mu kuro lori igba. Mo ja yin si niyen. Errk

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment