Omi teyin wo igbin awon omo ologun Nigeria lenu lale ojo Isegun to koja yii ni agbegbe Bulabulin Ngaura to wa ni Ijoba Ibile Damboa, Borno nibi ti awon omo Soja bi merindinlogun (16) ti feyin janle ti won ko si le dide mo.
Okan ninu awon Soja naa to sare wo ilu Maiduguri nigba ti ori iya re ko yo pade awon oniroyin pelu alaye bi isele naa se waye.
"We were totally subdued by the
insurgents." Bi soja yii se n soro bee lo n mi gulegule bi eni moto jaale. Bee si ni oju re ko rerin rara
"Some of my colleagues were abducted and many others escaped with bullet wounds.
Dozens of Boko Haram insurgents stormed our checkpoint at Bulabulin on Tuesday night.
"The terrorists came in a convoy of over 30 vehicles, mounted with Anti Aircraft guns (AA)."
"I was at the checkpoint when the terrorists came, we tried our best but they had advantage over us.
They had AA and we had Ak47 rifles that are not fully loaded. (Ibon awon omo Boko Haram lagbara ju ti awon omo ologun lo).
When we realised that they had taken over the place, some of us escaped to Maiduguri and other places but many could not make it.
"As I am talking to you, 16 bodies of our colleagues have been brought to Maiduguri, this is apart from those that sustained injuries and many others that are missing in action."
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment