Smiley face

Awon Nnkan Pataki Ti Eni Lati Mo Nipa Ebola

Orisiirisii iroyin eleje ni awon eniyan n gbe kaakiri nipa arun Ebola eleyii ti n fa eru ati aibale okan fun awon eniyan, paapa julo awon omo Nigeria.



Awon Yoruba ni eni moju Ogun laa ni o pabi n'Ire. Mo royin lati ma tele ohunkohun ti enikeni le wi fun yin nipa arun Ebola yala bi o se n ran eniyan tabi bi eniyan se le daabo bo ara re lowo ewu Ebola yato si ohun ti ajo Agbaye WHO- World Health Organization ba so fun wa.
E gbe owo le linki isale yii ki e le ri awon alaye itosona eleyii ti won fi ibeere ati idahun gbe kale lati owo ajo WHO: who.int/csr/disease/ebola/faq-ebola/en/
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment