Awon Yoruba ni omode to ba mowo we, dandan ni ko bagba jeun. Ninu igbesi aye eda, lara ohun to se pataki ni ibowo fun awon asiwaju
Smade, okan ninu awon onise alariya omo Nigeria to wa ni ilu London gba adura lenu Dadday Showkey. Tinutinu ni Daddy Showkey fi gbadura fun un, boya nitori bi okunrin naa se re ara re sile niwaju Showkey tabi tori wi pe o gbaa ni asiwaju.
Sebi ti omode ba laso bi agba, ko le ni akisa bi agba lailai.
0 comments:
Post a Comment