Idunnu awon abiyamo aye
ni wi pe aye ti esin won o je, ki iru idi won ri je. Bee gele lori pelu
awon omo Adeyemi Afolayan ti opolopo awon eniyan mo si Ade Love ninu
fiimu olokiki ti won pe akole re ni TAXI DRIVER.
Kunle
ati Gabriel ni yii, yato si wi pe won ko je ki ise baba won parun, ife
nla lo wa laaarin won, eleyii ti won n lo lati se iranwo fun ara won
lati tete moke ninu ise tiata.
Baba to bi Kunle, lobi Aremu oun naa lo bi Gebu ati Moji, ise tiata si ni gbogbo won se.


0 comments:
Post a Comment