Eniyan to ba ni iku Omoladun ko dun Babatunde Omidina, esi kankan soso ti Adimeru fi n da won lohun ni wi pe ki awon naa lo lu iyawo won pa.
Nibayii, Baba Suwe ti jewo fun awon oniroyin wi pe oun ti setan lati ni aya tuntun leyin odun marun-un ti 'Moladun ti lo.
Tani Iyawo Tuntun ti Baba Suwe setan lati fe?
Mo ti bere si ni fimu finle lati mo obirin tuntun naa, mo si fi da yin loju wi pe ko ni pe lu si mi lowo.

0 comments:
Post a Comment