Smiley face

Leta Lati Owo Ogbeni Gbenga F9 Parallel

Sii Olayemi Oniroyin,

E joo, mo niidi iranlowo yin ni o. Igba kefa re e ti mo n se idanwo WAEC 'F9' parallel ni won maa n fun mi ni gbogbo igba, oruko mi kii si se Fatai.

O wu mi lokan lati di dokita onimo isegun oyinbo lojo kan. Mo si gbagbo wi pe Olorun le lo mi lati wo arun HIV ati EBOLA, sugbon ogun amubo yii naa ni.

Se kii se wi pe awon aye wa nidi matter mi sa?
Kini ki n se gbogbo omo Nigeria?


Emi ni tiyin ni tooto,
Ogbeni Gbenga
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment