Sebi won ni eni ti ko ba sebi alaaru l'Oyingbo, ko le sebi Adegboro loja Oba. O seese ko je wi pe ohun ti oyinbo yii ropo ni yii to fi ronu lati wa maa gbaaru sanmonti ko le di eniyan pataki ti won yoo maa pe ni Adegboro.
Ok now, e je ka ti apa ibi yen bo si ibomii.
E joo, se e fe di star?
Ti e ba fe di star emi mo ona ti le gba di star. E mu Star meta lago meta osan fun igba meta, ale meta, oru meta, ojo meta, ose meta, osu meta fun odindin odun meta ati sentuuri meta.
Mo fi buredi ati akara ti mo je laaro yii bura, e maa di star lowo kan. E gba bee!
0 comments:
Post a Comment