Eniyan ti o korin fologbon o ni lati gbon bi Ifa.
Eni ori re pe kii gbe eran elede dele Alfa.
Sorosoro ti o jafafa, aye kii naja won.
To ba jo bi iro ologbon aye e ja mi.
GAAD ti kuro lomode oniwatawoto.
Gbogbo aye ni won dupe lowo Oluwa
Won ni Adeolu Ademola le lodun.
Adeolu Gboyega se ojo ibi inu awa dun gidi.
Happy Birthday!

0 comments:
Post a Comment