Leyin opolopo ebe, Ilu Israel ti fe maa 'gboju mba' bi asa Soji Omobanke pelu bi won se dawo akara iku ti won ju si Gaza duro nibi ti opolopo alaise ti n fori kata.
Sugbon gege bi oro awon agba, won ni ori ti o jeya laye ko ni salai ma jeya naa niwon igba ti won ba ti ko iya sinu file re lode orun.
Nibi ti Israel ti n si mi sara lati nnkan bi ojo meta seyin ni Palestine ti pada lo ju bombu lu won. Nibayii, Palestine ti lo fori jale agbon, afaimo ki agbon ma ta won pa pelu ado iku alaidawo duro ti Israel fi n ranse si won pada ni kikankikan.

0 comments:
Post a Comment