Ojo kinni osu kejo odun yii ni won pada si Quilox leyin ti agbo won ti fadi seyin lati lo tun agbara mu wa lakotun.
Gege bi iwadii, owo bi bilionu kan naira ni Ogbeni Shina Peller to je alaga ibudo afe naa na lati mu ogo Quilox di iyanu. Eleyii to mu wa laaarin awon ibudo afe olowo nla ni ile adulawo lapapo. Oju ona Ozumba Mbadiwe ni Victoria Island ni ile igbafe naa wa.
E pade mi nibe lale oni...










0 comments:
Post a Comment