Smiley face

Ajanaku Sun Ni Ilu Ibadan

Okan ninu ojulowo awon omo Ibadan, onisowo pataki to tun je okan lara awon agba oloye egbe APC, Otunba Lekan Abass la gbo wi pe o ku lojo kerindinlogun osu yii nigba to fe lo wo iyawo re, Folake Abass to dubule aisan ni osibitu Oritamefa, UCH, to wa ni ilu Ibadan

Eni odun mokanlelaadota (51) ni Otunba ki iku ojiji to mu lo sorun aremabo.

Ki Oba Oluwa fi orun ke e!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment