Losan oni, 18-09-14, awon eniyan ti won gbe ni abule Kamba to wa ni Ipinle Kebbi mu okunrin kan ti oruko re n je Adamu Gaya pelu bi won se fura sii wi pe oun lo fi omobirin ti won wa kan soogun.
Awon ara abule yii fe da sharia fun okunrin ti won fura si yii ni awon olopa ba ni "Noooo, don't take law into your hands'.
Oyinbo kekere ti awon olopa fo ni yii ni oro ba di gobe laaarin awon olopa ati awon ara abule ti ara n kan. Awon eniyan merin ni awon olopa ti pa bayii nigba ti aimoye ti wa ni atimole.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment