Awuyewuye oro kan ti n ja nile eleyii ti n wi pe awon agbaagba egbe APC fe fa Muhammed Buhari sile gege bi eni ti o soju egbe naa lati dije ipo Aare lodun 2015 ni Atiku to je igbakeji Aare ile yii nigba kan ri ti soro ba.
Gege bi oro re, o ni ala ti ko le se ni fun awon Olori egbe naa lati gbe iru igbese bee.
Die ni yii lara oro re:
"There is nothing like automatic ticket
and those people who are asking for automatic ticket might have been coming from a political background that did not know contest before.
"You know the APC is an amalgamation of a number of political parties that came together and merged their identities but the APC as
currently constituted cannot escape an elective mode of primaries.
"There is no zoning, on what basis are you going to say it is automatic?
There is no allocation as they do in the Peoples Democratic Party, there is nothing like that so, on what basis?"
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment