Okan ninu awon oludije fun ipo Gomina labe egbe oselu People's Democratic Party, PDP ni Ipinle Plateau, Senator Cosmas Niagwan, lagbo wi pe oku sinu ile re to wa ni Ipinle Eko.
Okunrin to ti fi igba kan je omo ile igbimo asofin lagbo wi pe o sun ni ko si pada ji saye mo.
E je ka gbo ohun ti ore re timotimo, Ogbeni Gabriel Nkup so nipa iku Senator Cosmas Niagwan:
"I spoke with his wife and she said that he did not show any sign of sickness, but went to bed and failed to wake up"
Iku okunrin yii mu ifura pupo dani eleyii to se opolopo awon eniyan ni kayeefi nla.
Nje oseese fun eniyan ti ko saisan ko to sun, kosi doju orun doju iku lai se wi pe eni bee ni ijamba moto loju orun?
Iroyin isele kayeefi yii ti mu mi bere ise iwadii tuntun nipa isoro ati iriri aye eda laye.
Ninu iwadii mi, enikan fun mi ni nomba yii: 07065865035. O ni nomba Alfa nla kan ni ti oruko re n je Sheu Salam. O ni Alfa naa ni imo nipa igbe aye eda ati isoro ti n koju omo eda ni duniyan. O ni Alfa naa ni imo lati salaye aditu ogbon ati iriri eleyii ti o se iranlowo fun ise iwadii mi.
Kini mo ba bo lodo Sheu Salam? Ekunrere alaye mbo laipe.
Adura mi ni wi pe ogun aye ko ni bori wa o, a si ni bo sowo aye. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment