Smiley face

Ibeere Ojo Isinmi Fun Kristeni?

Eniyan to je Kristeni ododo sugbon to wa pa isin ojo isinmi je lati se nnkan mii to pataki. Ti Jesu ba de ni akoko isin ojo isinmi (Sande), nje kristeni naa ti ko si ni ile ijosin le tele Jesu lo bi?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment