Awon Yoruba bo, won ni ola abata ni i modo san, ola baba omo ni i mu omo yanfanda.
Ayeye ami-eye aso oge ti won pe ni 2014 British Fashion Awards waye lojo kinni osu kejila odun [1-12-14] ni ilu London.
Nibi ayeye yii ni Abisola to je okan lara awon omo gomina Ipinle Oyo, Senator Abiola Ajimobi ti gbe yoju pelu aso oge arambara.
Odun 2010 ni Abisola se igbeyawo pelu Kolapo to je okan lara awon omo oloye nla ni ilu Ibadan, Kola Daisi.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment