Smiley face

Oruko Desmond Elliot Ti Jade Loju Opon Ifa Egbe APC

Gbajugbaja osere tiata Nollywood, Olusola Desmond Elliot ti jawe olubori ninu eto idibo abele egbe Onigbale lati soju ekun ijoba Surulere nile igbimo asofin Ipinle Eko lodun 2015.

Ninu iroyin mii to jo toke yii: Gbajugbaja onkorin emi, Kenny Saint Brown (KSB) fidiremi ninu eto idibo abele egbe APC lati soju ekun ijoba Ikeja nile igbimo asofin Ipinle Eko lodun 2015. Arabirin yii lagbo wi pe o figagbaga pelu Ogbeni Folajimi Mohammed to je omo okan lara awon oloye agba egbe APC, Lai Muhammed.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment