Smiley face

Awon Ololufe Jimi Agbaje Dide Soke Lati Ye J.K Si Ni Ilu London

Eni ti n dije fun ipo gomina ni ipinle Eko labe egbe oselu PDP, Jimi Agbaje lo pade awon ololufe re ni ilu London. Lara awon to tele lo lati ilu Nigeria ni alaga egbe PDP lapapo nigba kan ri, Alh Bamanga Tukur naa tele lo ki ipolongo re le rinle daada. Ka ma paro, awon aye n fe JK ni ilu London. Gbogbo ibeere ti won bi i pata lo dahun lai seku eleyii to wu opolopo lori ti won si bere si ni se ikowojo fun eto ipolongo ati igbiyanju re lati di gomina Ipinle Eko.
Ope fun  Dare Lasisi fun awon aworan oke yii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment