Nje a le gba wi pe Buhari nife awon elesin igbagbo abi ogbon awon oloselu lasan ni eleyii. Nitori lara esun ti awon egbe PDP fi kan GMB ni wi pe o seese ko da ofin Sharia kale nikete ti agbara ba bo si lowo tan. Abi ka gba wi pe ibaniloruko je lasan ni gbogbo atotonu egbe PDP nipa Buhari?
Kini ero yin?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)


0 comments:
Post a Comment