Smiley face

Kilode ti Awon Ewe Feran Ki Won Maa Naka Meji Soke?" -Buhari

O dabi eni wi pe Oga Buhari ko jasi. Lara poposinsin odun tuntun, Muhammadu Buhari pinnu lati lo akoko naa pelu awon omoomo re lati se ajoyo odun. Okan ninu foto to ya pelu awon omo naa, ajagunfeyinti ri okan ninu awon omo naa to naka meji soke lati fi swaga ninu foto naa. Ika meji yii jo Buhari loju pupo, o si n beere idi ti awon ewe fi feran iru asa tuntun bee. Oya, e fun baba lesi...



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment