Smiley face

Ẹgbẹ́ Gani Adams tí lọ gbalẹ̀ nílùú Dubai

Gani Adams, Aare Ona Kankafo ilé Yorùbá, tí ṣe ifilole ẹgbẹ́ OPU, eléyìí tí ṣe adape orúkọ fún egbe  OPC fún àwọn ìlú òkèèrè, siluu Dubai. Odunlade Adekola pelu aya re wa ni ilu Dubai ni àkókò náà , eléyìí to fún toko taya náà ní àǹfààní láti darapo mo agbarijo awon ọmọ Oodua to wa niluu Dubai.

Orisun fọ́tò: Olufemi Davies MetroNews

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment