Smiley face

Mo tẹ́lẹ̀ wí pé Buhari kò ni òye nípa ètò ọrọ̀-ajé - Obasanjo

"Mo mọ tẹ́lẹ̀ wí pé Buhari kò ni òye to péye nípa eto ọrọ-ajé ṣáájú ko di Aare. Èrò mi ni wí pé, yoo se àmúlò àwọn ènìyàn ọlọpọlọ tí wọn nimọ láti rán an lọ́wọ́ nígbà tó bá gorí oye."

Oloye Olusegun Obasanjo kabamọ nínú leta tuntun tó kọ sí Ààrẹ Buhari nípa bí eto ọrọ ajé Naijiria ṣe di akurẹtẹ

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment